Ọba onípele tí ipele ni ìjọba ìpínlẹ̀ Ọ̀wọ́ Ondo ń dunkoko ikú mọ́ ọmọ ọdún mọ́kànlélógún (21yrs) tí orúkọ rẹ ń jẹ Kehinde, Látàrí bí ó sọ sọ ọba lo fún òun lóyún tí ó sì ní kí òun ló ṣẹ́ oyún náà, bí bẹ́ẹ̀ kọ́, óun yóò fi ikú ṣe ifá jẹ.
Ifemide Kehinde odomobirin tó jẹ́ ẹni ọdún mokanlelogun ṣàlàyé nínú iforowero to ṣe pelu oniroyin ṣàlàyé irinajo ìfẹ́ tó wà láàrin òun àti ọba ipele tó fi yọrí sí oyún tí Kabiyesi sì kojale pé àyàfi ki òun lọ yọ oyún náà dànù.
Kehinde to jẹ́ ọmọ ọdún mokanlelogun to wá láti ìlú ipele ni ijoba ibile ọwọ ipinle Ondo ló ké gbàjarè síta pé ọba ilu òun tó fún òun lọ ní o fẹ pa òun báyìí bí ó ṣe ní dandan ni òun yọ oyún tí òun ní fún un, ṣùgbọ́n tí Kehinde sì fi àkéte kori wipe òun kò lè lọ yọ oyún. Nítorí pé kì í ṣe àdéhùn tó wà láàrin òun àti Kabiyesi nìyẹn, ó ní nígbà T Kabiyesi kò ẹnu ìfẹ́ sì òun, Kabiyesi sọ pé òun má fe òun láti ṣe ìyá kejì nínú ààfin ipele ni. O tesiwaju pé ọba lo kọ ẹnu ìfẹ́ sì òun pé òun fe òun ṣe ìyàwó kejì, Kehinde ni òun sì Gb láti ṣe ìyàwó kejì láàfin ipele. Kehinde ṣàlàyé pé oro ìfẹ́ tó wà láàrin oub àti Kabiyesi lọ yọrí sí oyún,Ti Kabiyesi sì sọ pé kí òun ló yọ oyún náà dànù.
Kehinde ni idunkoko iku ti oba dun mo òun ló jẹ́ kí òun padà lọ ba oyún náà jẹ́ láti ìgbà yẹn ni ẹ̀jẹ̀ tí ń da lára òun, tí ọba sì fi owó ran ọkàn lára àwọn òṣìṣẹ́ inú ààfin.
Nígbà mìíràn ọba ma nlo POS láti fi owo ránṣẹ́ sì mi, ọkàn mi ò bá oyún náà jé ṣùgbọ́n idunkoko iku ti oba dun mo mi ti poju ló jẹ́ kí lọ yọ oyún náà, pẹlu bí ọba ṣe fún àwọn kan Tomiwa àti Ọkùnrin tí orúkọ rẹ ń jé Kazeem pé kí wọ́n bù mi dunkoko mo mi àwọn ohun wọ́n wà nínú èrò ibanisoro mi níbi tí wọ́n ti dunkoko bẹ́ẹ̀ náà ni wọn sọ pé ilé ọmọ mi ti bá jẹ́.
Kehinde ló sọ bẹ́ẹ̀. Arabinrin kan náà sọ̀rọ̀ nípa Kabiyesi pé ìdí rẹ rèé tí òun náà kò fi fẹ́ Kabiyesi mọ pe ó ti nifẹ obìnrin ju, ó ní ojú ọba kí í rí obìnrin sójú gbogbo obìnrin ni ọba má kenu ìfẹ́ sí.
Ṣùgbọ́n báyìí gẹ́gẹ́ bí ohun tí Kehinde sọ pé àwọn olopaa ti bẹ̀rẹ̀ ìwádìí lórí oyún tí òun yọ, wọn ti gbéra lọ sí ilé ìwòsàn náà àti ibi tí òun ti lọ ra ogun iseyun tí òun ló láti yọ oyún inú òun látàrí bí ọba ṣe ń dunkoko ikú mọ́ òun.












Kayode Ibikunle
The king is a wicked man