Àwọn ènìyàn mẹ́rìnlélógún kú lẹ́yìn tí wọ́n mu ‘àgbo oògùn ìbílẹ̀ ’ ní Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ odigbo ìpínlẹ̀ Ondo.

Àwọn ènìyàn mẹ́rìnlélógún kú lẹ́yìn tí wọ́n mu ‘oògùn ìbílẹ̀ ’ kan ní Agbègbè Ìjọba Ìbílẹ̀ odigbo ìpínlẹ̀ Ondo. Ní…

Ka siwaju

Mo gbà ki jẹ koriko lábẹ́ aṣáájú Mùsùlùmí ju kí n jẹ ẹran-adìẹ lábẹ́ aṣáájú tí kì í ṣe Mùsùlùmí lọ’ — Onímọ̀ ẹ̀sìn Islam Almaliky ṣe àtìlẹ́yìn fún àjọṣepọ̀ Tinubu àti Shettima Muslim – Muslim ticket.

Mo gbà ki jẹ koriko lábẹ́ aṣáájú Mùsùlùmí ju kí n jẹ ẹran-adìẹ lábẹ́ aṣáájú tí kì í ṣe Mùsùlùmí…

Ka siwaju

Àwọn ọ̀daràn agbésùnmọ́mí gba 50 mílíọ̀nù náírà, àwọn ohun-mímu ẹlẹ́rìndòdò Malt àti oúnjẹ àti èso, kí wọ́n tó tú Adájọ́ Ilé-ẹjọ́ Gíga ti ìpínlẹ̀ Kebbi tí wọ́n jí gbé sílẹ̀ – Ìbátan rẹ̀ ṣàlàyé.

Àwọn ọ̀daràn agbésùnmọ́mí gba 50 mílíọ̀nù náírà, àwọn ohun-mímu ẹlẹ́rìndòdò Malt àti oúnjẹ èso kí wọ́n tó tú Adájọ́ Ilé-ẹjọ́…

Ka siwaju

Awọn Agbéṣùnmọ̀mí ji awọn ọmọ ile-iwe mẹjọ ti Gateway ICT Polytechnic gbe ni ipinlẹ Ogun, ile-iwe náà si fagilé àwọn ìdánwò tí wọ́n fẹ́ ṣe ni ọjọ́bọ̀ .

Awọn Agbéṣùnmọ̀mí ji awọn ọmọ ile-iwe mẹjọ ti Gateway ICT Polytechnic gbe ni ipinlẹ Ogun, ile-iwe náà si fagilé àwọn…

Ka siwaju

Àárẹ̀ ilẹ̀ Amẹ́ríkà, Donald Trump, gboriyin fun ọba Morocco Mohammed VI, fún aṣeyọrí iṣẹ́ òpópónà ńlá kìlómítà (1,055)Tiznit-Dakhla, O kede ni ọjọ́ aiku pé wọ́n yóò sọ ọ̀nà gíga Tiznit-Dakhla tí orilẹ-èdè Morocco ní orúkọ òun.

Trump kede pe wọn yoo fun ọna nla Tiznit–Dakhla ni orukọ rẹ, o si dupẹ lọwọ Ọba Mohammed VI. Ààrẹ…

Ka siwaju

Ile igbimo Aṣoju Pé Mínísítà fún Ọrọ Ajeji ati Olùdámọ̀ràn Ààbò Orilẹ-èdè (NSA) wá fún Ìbéèrè lori Ìwádìí PFIPC ti a pe ni ‘Eke’.

Ile igbimo Aṣoju Pé Mínísítà fún Ọrọ Ajeji ati Olùdámọ̀ràn Ààbò Orilẹ-èdè (NSA) wá fún Ìbéèrè lori Ìwádìí PFIPC ti…

Ka siwaju

Ecowas fọwọ́ sí àdéhùn Opó-ìgbékalẹ̀ Gaasi láàrin Morocco àti Nàìjíríà: ‘Iṣẹ́-àkànṣe fún ìran òde-òní àti ti ọjọ́-iwájú’ ń tẹ̀síwájú.

ECOWAS fọwọ́ sí àdéhùn fún ọ̀pá-ìgbàgáàsì (pipeline) láàrin Nàìjíríà àti Morocco ní Freetown Àjọ ECOWAS ti fọwọ́ sí àdéhùn láàrin…

Ka siwaju