Àwọn ẹlẹ́ṣọ àbò Aṣọ́gbó ti farapa yannayanna,Won pa ènìyàn méjì, tí wọ́n sì tún jí àwọn aráàlú gbé lọ ní ọsan gangan nígbà tí àwọn agbésùnmọ̀mí kọlù Oko Erese oro- àgọ́, Babanla Kwara.

Awọn ará ìlú ti o ba oníròyìn sọrọ sọ pe ìṣẹ̀lẹ̀ náà wáyé ni ọsan ọjọ ìṣẹ́gun, ọjọ́ kejìdnlogbon oṣù…

Ka siwaju

Fatimo ni agídí púpò ni a ṣe pa á nínú àhámọ́ , agbéṣùmọ̀mí pa ọkùnrin oníṣòwò àti ọmọ rẹ lẹ́yìn N12m

Lẹ́yìn owó ìtúsílẹ̀ N12 mílíọ̀nù àwọn agbésùnmọ̀mí PA arákùnrin oníṣòwò ńlá kan àti ọmọ rẹ̀ n’ilu Abuja.Fatima jẹ́ ọmọ ilé…

Ka siwaju