Ayẹyẹ Ọjọ àyájọ́ Awọn ọmọde àti EID tí ọdún ileya yìí : Gomina Ọyọ ṣe àdéhùn idaniloju pé awọn ọmọ ile-iwe ti wọn ji àti awọn olukọ ni igbiyanju ìtúsílẹ̀ wọn ti nlọ lọwọ.

Ayẹyẹ Ọjọ àyájọ́ Awọn ọmọde àti EID tí ọdún ileya yìí : Gomina Ọyọ ṣe àdéhùn idaniloju pé awọn ọmọ…

Ka siwaju

Ìròyìn ni yàjóyàjó:Ibanujẹ ni agbègbè Ọyọ wà bi àwọn obi ti fi agbára lọ mú àwọn ọmọ wọn ọmọdé kúrò ni ilé-ìwé alákọ́bẹ̀ẹ̀rẹ̀ nítorí àwọn ikọlu àwọn agbésùnmọ̀mí tí wọ́n ní o ń ṣẹlẹ̀ ni gbogbo agbègbè Ajawa ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ .

Àwọn òbí tí fi agbára lọ mú àwọn ọmọ wọn ọmọdé kúrò ni ilé ìwé nítorí àwọn ìṣẹ̀lẹ̀ ìkọlù agbésùnmọ̀mí…

Ka siwaju

Àwọn Agbéṣùmọ̀mí nílò owó láti dá àbó bó ara wọn lọ́wọ́ ipa ìjọba Nàìjíríà tó fẹ́ pa wọn ló jẹ́ kí wọ́n ma ṣe ìkọlù sí àwọn ìletò, jí àwọn ará ìlú gbé – Agbẹnusọ fún àwọn- agbésùnmọ̀mí Sheikh Gumi

Agbenusọ fún àwọn agbésùnmọ̀mí Islam kan, Sheikh Ahmad Gumi, ti sọ idi ti awọn darandaran ko fi le kuro nìdí…

Ka siwaju

Ààrẹ Tinubu bu ẹnu àtẹ́ lu bí àwọn agbesunmobi ṣe pa àwọn olùkọ́, tí wọ́n sì jí àwọn Akẹ́kọ̀ọ́, àti àwọn olùkọ́ mi-in gbé lọ ní ìjọba ìbílẹ̀ Oriire ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́.

Ààrẹ Tinubu bu ẹnu àtẹ̀ lu Olùkọ́ ti awon agbésùnmọ̀mí ṣekú pa ni ijoba ìbílè Oriire ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ , ó…

Ka siwaju

Àwọn Agbéṣùmọ̀mí ṣe ìkọlù sí Ilé ìwé mẹta ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ ní Ọ̀yọ́:ilé ìwé Baptist Nursery and Primary school, Community Grammar School Esiele àti L. A Primary school, wọn pa Olukọni, jí ọ̀gá àgbà àti ọ̀pọ̀ àwọn ọmọ ilé ìwé gbé lọ.

Awọn Agbéṣùmọ̀mí ṣe ìkọlù sí ile-iwe mẹta ọ̀tọ̀ọ̀tọ̀ ni ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ , wọ́n pa Olukọni,wọn ji Awọn ọmọ ile-iwe ati…

Ka siwaju