Ẹ lọ fa owó ìfipamọ́ yín yọ nílé ifowopamo kí ẹ sì ra àwọn ìbọn agbára-ńlá, láti dáàbò bo ara yín ni Aṣojú sòfin ìjọba ní Zamfara Hon. Abdulmalik Zubairu sọ fún àwọn ènìyàn agbègbè rẹ̀.

Ẹ lọ fa owó ìfipamọ́ yín yọ nílé ifowopamo kí ẹ sì ra àwọn ìbọn agbára-ńlá, láti dáàbò bo ara…

Ka siwaju

Sheikh Gumi bèrè ìdí tí kò fi sí òṣìṣẹ́ Ìjọba Tinubu kankan tí ó ti lọ pàdé awọn ọmọ ẹgbẹ ikọ̀ Boko Haram tàbí lọ bá àwọn ọlọ́ṣà agbésùmọ́mí fún ijiroro ìpàdé àlàáfíà , gẹ́gẹ́ bí Jonathan àti Osinbajo ti ṣe pẹ̀lú àwọn ọlọ̀tẹ̀ oníjàgídíjàgan agbègbè Niger Delta (Niger Delta militants) .

Sheikh Gumi bèrè ìdí tí kò fi sí òṣìṣẹ́ Ìjọba Tinubu kankan tí ó ti lọ pàdé awọn ọmọ ẹgbẹ…

Ka siwaju

Boko Haram kede iku oluyaworan wọn ti àwọn ọmọ ogun Nàìjíríà pa ninu ikọlu kan, Boko Haram ti kede iku Abu Salim al-Barnawi, oluyaworan kan ti awọn ọmọ-ogun Naijiria pa lakoko ikọlu kan.

Ni ọjọ́ kejìlelógún, oṣù keje ọdún 2026, ní àwọn ikọ̀ Boko Haram kede iku oluyaworan wọn ti wọn pa ninu…

Ka siwaju

‘A gbọ́ igbe olùkọ́ wa kí wọ́n tó pa á’: Akẹ́kọ̀ọ́ ilé-ìwé kan láti Ìbàdàn tí wọ́n gbà là ṣàlàyé nípa àwọn ìṣẹ́jú tó gbẹ̀yìn olùkọ́ Michael Oyedokun.

‘A gbọ́ igbe olùkọ́ wa kí wọ́n tó pa á’: Akẹ́kọ̀ọ́ ilé-ìwé kan láti Ìbàdàn tí wọ́n gbà là ṣàlàyé…

Ka siwaju

Àwọn agbésùnmọ́mí yawọ ilé ìwé girima ni Kogi nígbà tí àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ń ṣe ìdánwò NECO, wọ́n sì jí àwọn akẹ́kọ̀ọ́ mẹ́rin, olórí ilé ìwé, àti alábóòjútò ìdánwò gbé lọ .

Àwọn agbésùnmọ́mí afemisofo Yabo Ilé-ìwé ní Kogi Lakoko ti awọn akẹ́kọ̀ọ́ ń ṣe idanwo NECO, wọ́n jí ọ̀gá àgbà ilé…

Ka siwaju

Àwọn ọmọ ogun Nàìjíríà mú obìnrin ọmọ orilẹ-èdè Chad tí wọ́n fẹ̀sùn kàn pé ó ń fún àwọn agbésùmọ́mí Boko Haram àti ISWAP ní, oúnjẹ, oògùn olóró àti ọtí líle ní Borno.

Ọwọ́ àwọn ológun orilẹ-èdè Nàìjíríà ti tẹ arábìnrin kàn Racheal Samuel ẹni ọdun mejidinlaadota(48), ọmọ orílẹ̀ èdè Chad 🇹🇩 ,Owo…

Ka siwaju

Àwọn olùkọ́ ní Ọ̀yọ́ bẹ̀rẹ̀ iṣẹ́ wọn bí àníyàn ṣe ń pọ̀ sí lórí àwọn akẹ́kọ̀ọ́ àti olùkọ́ ti wọn ji gbé, Àwọn ilé ìwé ní ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ tún ti ṣí sílẹ̀ lónìí, bí Ẹgbẹ́ Àwọn Olùkọ́ ní Nàìjíríà ((NUT) ti kéde

Àwọn ilé ìwé gbogbogbò ní Ìpínlẹ̀ Oyo tún ṣí sílẹ̀ lónìí, bí Ẹgbẹ́ Àwọn Olùkọ́ ní Nàìjíríà ti kéde ní…

Ka siwaju

Alakoso Iléeṣẹ́ Ologun Amẹrikà ṣe abẹwo sí Nàìjíríà fún Ìfọwọ́sowọ́pọ̀ ìlọṣíwájú tí ètò ààbò ati ajọṣepọ láàrin orílẹ̀ èdè Nàìjíríà àti Amẹrikà ní ìgbìyànjú láti kojú àwọn agbésùmọ́mí.

Alakoso Ologun Amẹrikà ṣe abewo sí Nàìjíríà fún Ìfọwọ́sowọ́pọ̀ ìlọṣíwájú tí ètò ààbò ati ajọṣepọ láàrin orílẹ̀ èdè Nàìjíríà àti…

Ka siwaju

Ọba Salman Aweda tìlú Olayinka ti kú sí ìgbèkùn àhámọ́ àwọn agbésùnmọ̀mí tí won jigbe ni ijoba ìbílẹ̀ Ifelodun Kwara, lẹ́yìn ti awon ajinigbe béèrè fun Milionu mọ́kànlélógún náírà , ọ̀kadà Alùpùpù méjì àti epo Petiro.

Ọba Salman Aweda tìlú Olayinka ti kú sí ìgbèkùn àhámọ́ àwọn agbésùnmọ̀mí tí won jigbe ni ijoba ìbílẹ̀ Ifelodun Kwara,…

Ka siwaju