Ìjà to ń lọ lọ́wọ́ pẹ̀lú Israel – Iran, Amẹ́ríkà Russia – Ukraine jẹ́ kí ó nira fún Ìjọba Nàìjíríà láti kojú àwọn agbéṣùmọ̀mí – Mínísítà fún ètò àbò Christopher Musa.

Ìjà to ń lọ lọ́wọ́ pẹ̀lú Israel – Iran, Amẹ́ríkà Russia – Ukraine jẹ́ kí ó nira fún Ìjọba Nàìjíríà…

Ka siwaju

Gómìnà Katsina Radda ní kí àwọn agbésùnmọ̀mí gbé ohun ìjà ọwọ́ wọn sílẹ̀, kí wọ́n padà sí ọ̀dọ̀ àwọn ẹbí wọn gẹ́gẹ́ bí ìjọba ṣe ṣèlérí àtitìlẹ́yìn.

Gómìnà Katsina Radda ní kí àwọn agbésùnmọ̀mí gbé ohun ìjà ọwọ́ wọn sílẹ̀, kí wọ́n padà sí ọ̀dọ̀ àwọn ẹbí…

Ka siwaju

Àwọn Ọlọ́pàá ri aṣọ ọlọ́pàá méjì gba lọwọ awọn afurasi awọn Fulani ajinigbe ni ìpínlẹ̀ Ogun, ti wọn si ti pa awọn èèyàn méjì ni Ẹdo .

Oṣu Kẹfa Ọjọ Kẹfà , Ọdun 2026IroyinOrúkọ Àwọn afurasí méjì náà ni Gafaru Adamu, ẹni ọdun marundinlogbon 25 ati Muhammed…

Ka siwaju

Awọn Agbéṣùmọ̀mí ji Olukọni Shina Adeoye tí Ile-iwe alakọbẹrẹ Cooperative Primary school Eruku Kwara gbé ni ọna rẹ bí ó ṣe ń lọ síbi iṣẹ.

Awọn Agbéṣùmọ̀mí ji Olukọni Shina Adeoye tí Ile-iwe alakọbẹrẹ Cooperative Primary school Eruku Kwara gbé ni ọna rẹ bí ó…

Ka siwaju

Àwọn olùjọsìn ECWA márùn-ún tí wọn jí gbé nílùú Omugo Kwara, pẹ̀lú Ìyàwó Pásítọ̀ ti kú sí ìgbèkùn àhámọ́ àwọn agbésùnmọ̀mí.

Àwọn olùjọsìn ECWA márùn-ún tí wọn jí gbé nílùú Omugo Kwara, pẹ̀lú Ìyàwó Pásítọ̀ ti kú sí ìgbèkùn àhámọ́ àwọn…

Ka siwaju

NYSC lè awọn ọmọ ẹgbẹ àgùnbánirọ̀ Corps kuro ni ìjọba Kaiama LGA Kwara nítorí ìbẹ̀rù bojo àwọn Bokoharam ń gbèrò láti ṣe ìkọlù tuntun mìíràn sí agbègbè náà.

Lónìí tíì ṣe ọjọ́ ajé ọjọ́ ìkíni oṣù Kàrún ọdún 2026 yii, ní NYSC lè awọn ọmọ ẹgbẹ àgùnbánirọ̀ Corps…

Ka siwaju