Remi Tinubu ṣayẹyẹ ẹ̀jẹ̀ lágbàáyé àwọn oluranlọwọ dídá ẹ̀jẹ̀ jọ fún àwọn aláìsàn,ó rọ awọn ọmọ Nàìjíríà lati ran àwọn aláìsàn lọ́wọ́ nípa ẹ̀jẹ̀ gba ẹbun atinuwa

Remi Tinubu ṣayẹyẹ ẹ̀jẹ̀ lágbàáyé àwọn oluranlọwọ dídá ẹ̀jẹ̀ jọ fún àwọn aláìsàn,ó rọ awọn ọmọ Nàìjíríà lati ran àwọn…

Ka siwaju

Ìjọba ìpínlẹ̀ Èkìtì ti kéde ìsinmi lenu isẹ fún àwọn òṣìṣẹ́ lónìí tíì ṣe ọjọ́ Ẹtì, ọjọ́ kọ̀ọ̀kandinlọ́gún oṣù kẹfà Ọdun 2026.

Ìjọba ìpínlẹ̀ Èkìtì ti kéde ìsinmi lenu isẹ fún àwọn òṣìṣẹ́ lónìí tíì ṣe ọjọ́ Ẹtì, ọjọ́ kọ̀ọ̀kandinlọ́gún oṣù kẹfà…

Ka siwaju

Àwọn olóyè ilẹ̀ Ìbàdàn rọ olùdíje fún ipò Gómìnà Ọ̀yọ́ lábẹ́ asia ẹgbẹ́ APC Alli Sharafadeen láti ṣe pàtàkì ipá ti oyè ìbílẹ̀ ju erongba olóṣèlú lọ.

Àwọn olóyè rọ olùdíje fún ipò Gómìnà Ọ̀yọ́ lábẹ́ APC Alli Sharafadeen láti ṣe pàtàkì ipá ti oyè ìbílẹ̀ ju…

Ka siwaju

Ọba Salman Aweda tìlú Olayinka ti kú sí ìgbèkùn àhámọ́ àwọn agbésùnmọ̀mí tí won jigbe ni ijoba ìbílẹ̀ Ifelodun Kwara, lẹ́yìn ti awon ajinigbe béèrè fun Milionu mọ́kànlélógún náírà , ọ̀kadà Alùpùpù méjì àti epo Petiro.

Ọba Salman Aweda tìlú Olayinka ti kú sí ìgbèkùn àhámọ́ àwọn agbésùnmọ̀mí tí won jigbe ni ijoba ìbílẹ̀ Ifelodun Kwara,…

Ka siwaju

Olùdíje fún ipò Gómìnà Ọ̀yọ́ lábẹ́ asia ẹgbẹ́ òṣèlú Accord , Oriyomi Hamzat, Tako ẹ̀sùn tí wọ́n fi kàn pé ó ní àwọn ọna asopọ Kan si Afurasí adigunjalè ‘Surri Ilupeju’.

Olùdíje fún ipò Gómìnà Ọ̀yọ́ lábẹ́ asia ẹgbẹ́ òṣèlú Accord , Oriyomi Hamzat, Tako ẹ̀sùn tí wọ́n fi kàn pé…

Ka siwaju