Àwọn olùjọsìn ECWA márùn-ún tí wọn jí gbé nílùú Omugo Kwara, pẹ̀lú Ìyàwó Pásítọ̀ ti kú sí ìgbèkùn àhámọ́ àwọn agbésùnmọ̀mí.

Àwọn olùjọsìn ECWA márùn-ún tí wọn jí gbé nílùú Omugo Kwara, pẹ̀lú Ìyàwó Pásítọ̀ ti kú sí ìgbèkùn àhámọ́ àwọn…

Ka siwaju

Awọn agbebọn ji iyawo,àti awọn ọmọ ibeji arákùnrin àbúrò minisita fún ètò iná mọ̀nàmọ́ná tẹlẹri Adebayo Adelabu gbé lọ nilu Ìbàdàn ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́.

Awọn agbebọn ji iyawo,àti awọn ọmọ ibeji arákùnrin àbúrò minisita fún ètò iná mọ̀nàmọ́ná tẹlẹri Adebayo Adelabu gbé lọ nilu…

Ka siwaju

NYSC lè awọn ọmọ ẹgbẹ àgùnbánirọ̀ Corps kuro ni ìjọba Kaiama LGA Kwara nítorí ìbẹ̀rù bojo àwọn Bokoharam ń gbèrò láti ṣe ìkọlù tuntun mìíràn sí agbègbè náà.

Lónìí tíì ṣe ọjọ́ ajé ọjọ́ ìkíni oṣù Kàrún ọdún 2026 yii, ní NYSC lè awọn ọmọ ẹgbẹ àgùnbánirọ̀ Corps…

Ka siwaju

Awọn ọmọ ile-iwe ń ṣubu lulẹ̀ lakoko ayẹyẹ àyájọ́ Ọjọ Awọn ọmọde, Ọ̀pọ̀ àwọn ọmọdé, ọmọ ilé ìwé ló dákú, bí wọn ṣe yín Tajútajú nibi ayẹyẹ àyájọ́ Awọn ọmọde ni . Edo.

Iberu lo wa ni papa isere Samuel Ogbemudia, lojoru Wesde, nigba ti a gbo wi pe awon akekoo kan subu…

Ka siwaju

Idunnu nla ṣubú layọ̀ ni olu ilé-iṣẹ́ APC lórí bí Tinubu ṣe jáwé olubori nínú ètò ìdìbò abẹ́lé fún ipò Ààrẹ orílẹ̀ Nàìjíríà .

Lónìí tíì ṣe ọjọ́ Àbámẹ́ta, ọjọ́ ketalelogun oṣù Kàrún ọdún 2026 yii, ní Nàìjíríà dibo abẹ́lé fún ipò Ààrẹ orílẹ̀…

Ka siwaju