Ìròyìn pàtàkì : Kaiama KwaraÀwọn obìnrin àti ọmọdé mẹ́rindínlọ́gọ́sàn 176 tí àwọn agbésùnmọ́mí jí gbé láti àdúgbò Woro, Nuku ní ìpínlẹ̀ Kwara ti gba ìtúsílẹ̀ òmìnira wọn padà lẹ́yìn oṣù mẹ́fà.

Àwọn ènìyàn mẹ́rindínlọ́gọ́sàn 176 ti àwọn agbésùnmọ́mí ji gbé láti àwọn agbègbè Woro ati Nuku, ìjọba ìbílẹ̀ Kaiama ni Ìpínlẹ̀…

Ka siwaju

Ìjọba Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ ti fìdí rẹ̀ múlẹ̀ pé àwọn ọkọ̀ òfuurufú méjì tí wọ́n rà fún iṣẹ́ àbò àti láti mú kí gbígbà ìròyìn àṣírí nípa ọ̀rọ̀ àbò láàrin ìpínlẹ̀ náà túbọ̀ lágbára ti dé.

Gómìnà Makinde sọ pé wọ́n ra ọkọ̀ òfuurufú náà láti lè máa gba ìwífún láti ojú ọ̀run káàkiri Ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́;…

Ka siwaju

Iléeṣẹ́ ọlọ́pàá ní ìpínlẹ̀ Ondo mú àwọn ọ̀daràn mẹ́ta tí wọ́n máa ń ja àwọn ènìyàn ní olè lọ́nà, wọ́n gba àwọn ìbọn àti ọkọ̀ lọ́wọ́ wọn, wọ́n sì tún mú àwọn afurà méje mìíràn.

Ogunjọ́ 20 Oṣù Keje, Ọdún 2026ÌròyìnÓ sọ pé wọ́n dá àwọn afurasi náà dúró nígbà tí wọ́n ń rìnrìn-àjò nínú…

Ka siwaju

Àwọn oníjàgídíjàgan agbésùnmọ́mí tú wa sílẹ̀ kí àwọn ọmọ-ogun Nàìjíríà tó mú wa padà sílé – ọkàn lára Olùkọ́ láti Ọ̀yọ́ tí wọ́n gbà là sọ̀rọ̀.

Àwọn oníjàgídíjàgan agbésùnmọ́mí tú wa sílẹ̀ kí àwọn ọmọ-ogun Nàìjíríà tó mú wa padà sílé – ọkàn lára Olùkọ́ láti…

Ka siwaju

Àjọ tó ń kojú ọ̀rọ̀ oògùn olóró ní Nàìjíríà NDLEA mú obìnrin ọmọ orílẹ̀-èdè Chad kan tó jẹ́ ẹni ọgọ́rin ọdún , tí wọ́n sì ń fẹ̀sùn kàn pé ó ń ta oògùn olóró, nígbà tí wọ́n ń ṣe ìgbésẹ̀ kárí-ìlẹ̀ láti dènà irú ìwà bẹ́ẹ̀.

Àjọ tó ń kojú ọ̀rọ̀ oògùn olóró ní Nàìjíríà NDLEA mú obìnrin ọmọ orílẹ̀-èdè Chad kan tó jẹ́ ẹni ọgọ́rin…

Ka siwaju

Gomina Kwara AbdulRazaq tó jẹ́ ọmọ Fulani dá wa dúró kò fàyè gba wa , láti bá àwọn agbésùnmọ̀mí jà lé wọn kúrò nínú igbó Kwara — Ìrú Ekun eléso ààbò ti Sunday Igboho.

Gomina Kwara AbdulRazaq jẹ́ ọmọ Fulani dá wa dúró kò fàyè gba wa , láti bá àwọn agbésùnmọ̀mí jà lé…

Ka siwaju

Àwọn agbésùnmọ́mí yawọ ilé ìwé girima ni Kogi nígbà tí àwọn akẹ́kọ̀ọ́ ń ṣe ìdánwò NECO, wọ́n sì jí àwọn akẹ́kọ̀ọ́ mẹ́rin, olórí ilé ìwé, àti alábóòjútò ìdánwò gbé lọ .

Àwọn agbésùnmọ́mí afemisofo Yabo Ilé-ìwé ní Kogi Lakoko ti awọn akẹ́kọ̀ọ́ ń ṣe idanwo NECO, wọ́n jí ọ̀gá àgbà ilé…

Ka siwaju

Àwọn ọlọ́pàá Nàìjíríà gba àwọn akẹ́kọ̀ọ́ mẹ́ta tí wọ́n jí gbé ní Ẹdo sílẹ̀ , wọ́n sì pa ẹni tí wọ́n fura sí pé ó jí wọn gbé.

Àwọn ọlọ́pàá Nàìjíríà gba àwọn akẹ́kọ̀ọ́ mẹ́ta tí wọ́n jí gbé ní Ẹdo sílẹ̀ , wọ́n sì pa ẹni tí…

Ka siwaju

Gbogbo ọmọ ogun Nàìjíríà tó bá dúró de àṣẹ kí ó tó yinbọn pa àwọn apànìyàn agbésùmọ́mí ni wọ́n máa ń ṣe bí ọlọ́ṣà – Minisita fún ààbò Musa Christopher

Gbogbo ọmọ ogun Naijiria tó bá dúró de àṣẹ kí ó tó yinbọn sí àwọn apànìyàn agbésùmọ́mí ni wọ́n máa…

Ka siwaju