‘Ẹ jọ̀wọ́, ẹ ṣàánú wa’: Àwọn ẹbí,, ìyá bàbá rawọ ẹ̀bẹ̀ fún Gómìnà àti Emir Ilorin ìpínlẹ̀ Kwara láti gba àwọn ọmọ tí àwọn agbésùnmọ́mí jí gbé là.Ẹ jọ̀wọ́, ẹ ṣàánú wa’: Àwọn ẹbí,, ìyá bàbá rawọ ẹ̀bẹ̀ fún Gómìnà àti Emir Ilorin ìpínlẹ̀ Kwara láti gba àwọn ọmọ tí àwọn agbésùnmọ́mí jí gbé là.

‘Ẹ Jọ̀wọ́, Ẹ Ṣe Àánú Fún Wa’: Àwọn Ìdílé Bẹ̀bẹ̀ fún Gómìnà Kwara àti Emir Láti Gba Àwọn Ọmọ tí…

Ka siwaju

Ẹgbẹ́ kan ní Ilorin kọ̀ láti gba ẹgbẹ́ ààbò Sunday Igboho tí wọ́n ń pè ní ‘Iru Ekun’, wọ́n sì tọ́ka sí àwọn àníyàn nípa èrò láti dá Orílẹ̀-èdè Yorùbá sílẹ̀.

Ẹgbẹ́ kan ní Ilorin kọ̀ láti gba ẹgbẹ́ ààbò Sunday Igboho tí wọ́n ń pè ní ‘Iru Ekun’, wọ́n sì…

Ka siwaju

Àwọn agbésùnmọ́mí pa ènìyàn kan, jí ènìyàn kan gbé lọ , ọ̀pọ̀ ènìyàn sì farapa yánnayànna nínú ìkọlù tuntun kan tó wáyé ní àdúgbò kan ní Kwara.

Àwọn agbésùnmọ́mí pa ènìyàn kan, jí ènìyàn kan gbé lọ , ọ̀pọ̀ ènìyàn sì farapa yánnayànna nínú ìkọlù tuntun kan…

Ka siwaju

Gomina Kwara AbdulRazaq tó jẹ́ ọmọ Fulani dá wa dúró kò fàyè gba wa , láti bá àwọn agbésùnmọ̀mí jà lé wọn kúrò nínú igbó Kwara — Ìrú Ekun eléso ààbò ti Sunday Igboho.

Gomina Kwara AbdulRazaq jẹ́ ọmọ Fulani dá wa dúró kò fàyè gba wa , láti bá àwọn agbésùnmọ̀mí jà lé…

Ka siwaju

Ọba Salman Aweda tìlú Olayinka ti kú sí ìgbèkùn àhámọ́ àwọn agbésùnmọ̀mí tí won jigbe ni ijoba ìbílẹ̀ Ifelodun Kwara, lẹ́yìn ti awon ajinigbe béèrè fun Milionu mọ́kànlélógún náírà , ọ̀kadà Alùpùpù méjì àti epo Petiro.

Ọba Salman Aweda tìlú Olayinka ti kú sí ìgbèkùn àhámọ́ àwọn agbésùnmọ̀mí tí won jigbe ni ijoba ìbílẹ̀ Ifelodun Kwara,…

Ka siwaju

Àwọn olùjọsìn ECWA márùn-ún tí wọn jí gbé nílùú Omugo Kwara, pẹ̀lú Ìyàwó Pásítọ̀ ti kú sí ìgbèkùn àhámọ́ àwọn agbésùnmọ̀mí.

Àwọn olùjọsìn ECWA márùn-ún tí wọn jí gbé nílùú Omugo Kwara, pẹ̀lú Ìyàwó Pásítọ̀ ti kú sí ìgbèkùn àhámọ́ àwọn…

Ka siwaju

Àwọn asofin ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ Kọ̀ jálẹ̀ láti dúnàdúrà pẹ̀lú àwọn agbéṣùmọ̀mí tó jí àwọn ọmọ ilé ìwé àti àwọn olùkọ́ gbé lọ ní ìjọba ìbílẹ̀ Oriire ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́.

Àwọn asofin ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́ Kọ̀ jálẹ̀ láti dúnàdúrà pẹ̀lú àwọn agbéṣùmọ̀mí tó jí àwọn ọmọ ilé ìwé àti àwọn olùkọ́…

Ka siwaju

Ènìyàn mẹ́wàá ni wọ́n pa, Iléeṣẹ́ Ọlọ́pàá Kwara Fidi Ikolu tí awon agbésùnmọ̀mí ṣe múlẹ̀ ni àárín-òru si agbègbè Yashikira Kwara, ààfin Emir jona, wọ́n jí awon ènìyàn mẹ́wàá gbé lọ.

Iléeṣẹ́ Ọlọ́pàá Kwara Fidi Ikolu awon agbésùnmọ̀mí ni àárín-òru si adugbo Yashikira Kwara, Won so wipe ààfin Emir ti jona,…

Ka siwaju