Àárẹ̀ ilẹ̀ Amẹ́ríkà, Donald Trump, gboriyin fun ọba Morocco Mohammed VI, fún aṣeyọrí iṣẹ́ òpópónà ńlá kìlómítà (1,055)Tiznit-Dakhla, O kede ni ọjọ́ aiku pé wọ́n yóò sọ ọ̀nà gíga Tiznit-Dakhla tí orilẹ-èdè Morocco ní orúkọ òun.

Trump kede pe wọn yoo fun ọna nla Tiznit–Dakhla ni orukọ rẹ, o si dupẹ lọwọ Ọba Mohammed VI. Ààrẹ…

Ka siwaju

Ecowas fọwọ́ sí àdéhùn Opó-ìgbékalẹ̀ Gaasi láàrin Morocco àti Nàìjíríà: ‘Iṣẹ́-àkànṣe fún ìran òde-òní àti ti ọjọ́-iwájú’ ń tẹ̀síwájú.

ECOWAS fọwọ́ sí àdéhùn fún ọ̀pá-ìgbàgáàsì (pipeline) láàrin Nàìjíríà àti Morocco ní Freetown Àjọ ECOWAS ti fọwọ́ sí àdéhùn láàrin…

Ka siwaju

Orílẹ̀ èdè Morocco tí borí South Africa bí Morocco ṣe gba ipò kinni nínú ètò ọrọ ajé, ìdàgbàsókè inú ìlú, ilé isẹ, isẹ ìṣelọ́pọ̀ jẹ́ olùdarí ni gbogbo ilẹ̀ Afrika.

Orílẹ̀ èdè Morocco tí borí South Africa bí Morocco ṣe gba ipò kinni nínú ètò ọrọ ajé, ìdàgbàsókè inú ìlú,…

Ka siwaju