Ecowas fọwọ́ sí àdéhùn Opó-ìgbékalẹ̀ Gaasi láàrin Morocco àti Nàìjíríà: ‘Iṣẹ́-àkànṣe fún ìran òde-òní àti ti ọjọ́-iwájú’ ń tẹ̀síwájú.

ECOWAS fọwọ́ sí àdéhùn fún ọ̀pá-ìgbàgáàsì (pipeline) láàrin Nàìjíríà àti Morocco ní Freetown Àjọ ECOWAS ti fọwọ́ sí àdéhùn láàrin…

Ka siwaju

Ènìyàn mẹ́wàá ni wọ́n pa, Iléeṣẹ́ Ọlọ́pàá Kwara Fidi Ikolu tí awon agbésùnmọ̀mí ṣe múlẹ̀ ni àárín-òru si agbègbè Yashikira Kwara, ààfin Emir jona, wọ́n jí awon ènìyàn mẹ́wàá gbé lọ.

Iléeṣẹ́ Ọlọ́pàá Kwara Fidi Ikolu awon agbésùnmọ̀mí ni àárín-òru si adugbo Yashikira Kwara, Won so wipe ààfin Emir ti jona,…

Ka siwaju

Gómìnà Ìpínlẹ̀ Kwara Abdrahman kéde pé òun yóò san N20milionu fún ẹnì kọ̀ọ̀kan àwọn ológun mẹta tí àwọn agbésùnmọ̀mí pa ni ọgbà ológun kemanji Kwara.

Gómìnà Ìpínlẹ̀ Kwara Abdrahman tí ṣe ìpinnu pé òun yóò san N20m fún ẹnì kọ̀ọ̀kan àwọn ọmọ ogun Nàìjíríà mẹta…

Ka siwaju