Àwọn Ọlọ́pàá ri aṣọ ọlọ́pàá méjì gba lọwọ awọn afurasi awọn Fulani ajinigbe ni ìpínlẹ̀ Ogun, ti wọn si ti pa awọn èèyàn méjì ni Ẹdo .

Oṣu Kẹfa Ọjọ Kẹfà , Ọdun 2026IroyinOrúkọ Àwọn afurasí méjì náà ni Gafaru Adamu, ẹni ọdun marundinlogbon 25 ati Muhammed…

Ka siwaju

Boko Haram gé orí àwọn ọmọ ogún Nàìjíríà, àwọn kan farapa yánnayànna bí wọ́n ṣe ṣe Ìkọlù sí ọgbà ológun ni kùtùkùtù òwúrọ̀ òní ọjọ́ Ẹtì ni ibùdó àwọn ọmọ ogun tó wà ni ìpínlè Borno.

Loni tíì ọjọ́ Ẹtì ọjọ́ Kàrún oṣù kẹfà ọdún 2026 ni àwọn Boko Haram gé orí àwọn ọmọ ogún Nàìjíríà,…

Ka siwaju

Àwọn Ọlọ́pàá Ogun Mú Arákùnrin Kan Lórí Fídíò òfégè(Viral ‘Fake) Video’ ti o ń sọ pé àwọn agbésùmọ́mí ṣe Ìkọlù sí Owode-Idiroko.

Lónìí tíì ṣe ọjọ́bọ̀ ọjọ́ kẹrin oṣù kẹfà ọdún 2026, ní Àwọn Ọlọ́pàá Ogun Mú Arákùnrin Kan Lórí Fídíò òfégè(Viral…

Ka siwaju

Àwọn olùjọsìn ECWA márùn-ún tí wọn jí gbé nílùú Omugo Kwara, pẹ̀lú Ìyàwó Pásítọ̀ ti kú sí ìgbèkùn àhámọ́ àwọn agbésùnmọ̀mí.

Àwọn olùjọsìn ECWA márùn-ún tí wọn jí gbé nílùú Omugo Kwara, pẹ̀lú Ìyàwó Pásítọ̀ ti kú sí ìgbèkùn àhámọ́ àwọn…

Ka siwaju

Ilé Ẹjọ́ Gíga Jù Lọ ti ìjọba àpapọ̀ ti dájọ́ ikú fún àwọn agbésùnmọ̀mí Al-Shabaab mẹ́rin to ṣe ìkọlù ìpakúpa tí wọ́n pa àwọn olùjọsìn ní Ṣọ́ọ̀ṣì St. Francis Kátólíìkì tìlú Ọ̀wọ̀.

Ilé Ẹjọ́ Gíga Jù Lọ ti ìjọba àpapọ̀ ti dájọ́, ìdájọ́ ikú fún àwọn agbésùnmọ̀mí Al-Shabaab mẹ́rin lórí ìpakúpa tí…

Ka siwaju

Awọn agbebọn ji iyawo,àti awọn ọmọ ibeji arákùnrin àbúrò minisita fún ètò iná mọ̀nàmọ́ná tẹlẹri Adebayo Adelabu gbé lọ nilu Ìbàdàn ìpínlẹ̀ Ọ̀yọ́.

Awọn agbebọn ji iyawo,àti awọn ọmọ ibeji arákùnrin àbúrò minisita fún ètò iná mọ̀nàmọ́ná tẹlẹri Adebayo Adelabu gbé lọ nilu…

Ka siwaju