Jayden Adams, agbabọọlu ọmọ orilẹ-ede South Africa ti ku sí Cape Town lẹhin ti o farahan ninu idije eré ÌFẸSẸ̀WỌ́SẸ́ bọ́ọ́lù agbaye, awọn ọlọpa bẹrẹ iwadii.

Jayden Adams, agbabọọlu ọmọ orilẹ-ede South Africa ti ku ni Cape Town lẹhin ti o farahan ninu idije eré ÌFẸSẸ̀WỌ́SẸ́…

Ka siwaju

Àwọn ọlọ́pàá ilẹ̀ Gúúsù Áfíríkà(South Africa) ṣe àtìlẹ́yìn fún àwọn olùfẹ́hónúhàn olùfẹ̀sùn láìsí pípa wọ́n,’ akọ̀ròyìn CNN sọ fún Nàìjíríà, Kẹ́ńyà, àti àwọn ilẹ̀ Afrika mìíràn láti kọ́ ẹ̀kọ́ lórí ohun tó ṣẹlẹ̀ ni South Africa .

Àwọn ọlọ́pàá ilẹ̀ Gúúsù Áfíríkà(South Africa) ṣe àtìlẹ́yìn fún àwọn olùfẹ́hónúhàn olùfẹ̀sùn láìsí pípa wọ́n,’ akọ̀ròyìn CNN sọ fún Nàìjíríà,…

Ka siwaju

Awọn ikọlu Xenophobic: Awọn ọmọ orilẹ-èdè Nàìjíríà 700 tun wa ni ìdàmú ni South Africa ti wọn ti rí ọkọ̀ òfurufú tí yóò gbé wọn àkókò gbedeke tí South Africa fún wọn ti ń parí.

Awọn ikọlu Xenophobic: Awọn ọmọ orilẹ-èdè Nàìjíríà 700 tun wa ni ìdàmú ni South Africa ti wọn ti rí ọkọ̀…

Ka siwaju

Ijoba Nàìjíríà tí kó ipele Keji àwọn ọmọ orílẹ̀ -èdè Nàìjíríà jáde kúrò ni South Africa Nítorí ìkọlù Xenophobic, wọ́n ti dé sí Èkó.

Ijoba Nàìjíríà tí kó ipele Keji àwọn ọmọ orilẹ-ede Nàìjíríà jáde kúrò ni South Africa Nitori ikọlu Xenophobic, wọ́n ti…

Ka siwaju

Orílẹ̀ èdè Morocco tí borí South Africa bí Morocco ṣe gba ipò kinni nínú ètò ọrọ ajé, ìdàgbàsókè inú ìlú, ilé isẹ, isẹ ìṣelọ́pọ̀ jẹ́ olùdarí ni gbogbo ilẹ̀ Afrika.

Orílẹ̀ èdè Morocco tí borí South Africa bí Morocco ṣe gba ipò kinni nínú ètò ọrọ ajé, ìdàgbàsókè inú ìlú,…

Ka siwaju

Ẹ gé iléeṣẹ́ MTN àti DSTV South Africa, Sínetọ̀ Adams Oshiomhole rọ ìjọba pé kí ó yọ iléeṣẹ́ MTN, DSTV kúrò to jẹ́ ti South Africa àti ìwé àṣẹ wọn látàrí fífi ẹ̀mí ọmọ Nàìjíríà ṣòfò.

Sínetọ̀ Adams Oshiomhole rọ ìjọba pé kí ó yọ iléeṣẹ́ MTN, DSTV kúrò to jẹ́ ti South Africa àti ìwé…

Ka siwaju