Tinubu sọ fún Gómìnà Ademola Adeleke lórí ìpè fóònù pé òun ti pàṣẹ fún EFCC láti ṣí àkọọ́lẹ̀ ifowopamo owó ìjọba ìpínlẹ̀ Osun tí wọ́n ti pa tẹ́lẹ̀ sílẹ̀ .

Tinubu sọ fún Adeleke nípasẹ̀ ìpè lórí fóònù pé òun ti pàṣẹ fún EFCC láti ṣí àkọọ́lẹ̀ ifowopamo owó ìjọba…

Ka siwaju

Sheikh Gumi bèrè ìdí tí kò fi sí òṣìṣẹ́ Ìjọba Tinubu kankan tí ó ti lọ pàdé awọn ọmọ ẹgbẹ ikọ̀ Boko Haram tàbí lọ bá àwọn ọlọ́ṣà agbésùmọ́mí fún ijiroro ìpàdé àlàáfíà , gẹ́gẹ́ bí Jonathan àti Osinbajo ti ṣe pẹ̀lú àwọn ọlọ̀tẹ̀ oníjàgídíjàgan agbègbè Niger Delta (Niger Delta militants) .

Sheikh Gumi bèrè ìdí tí kò fi sí òṣìṣẹ́ Ìjọba Tinubu kankan tí ó ti lọ pàdé awọn ọmọ ẹgbẹ…

Ka siwaju

Ìjọba Nàìjíríà ya owó tó tó bíi bílíọ̀nù mẹ́jọ àti mílíọ̀nù márùndínláàádọ́ta (N8.05B)sọ́tọ̀ láti kọ́ tàbí ṣe àtúnṣe àwọn ṣọ́ọ̀ṣì àti mọ́sálásí láàrin àkókò tí orílẹ̀-èdè náà dojú kọ ìṣòro gbèsè.

Ìjọba Nàìjíríà ya owó tó tó bíi bílíọ̀nù mẹ́jọ àti mílíọ̀nù márùndínláàádọ́ta (N8.05B)sọ́tọ̀ láti kọ́ tàbí ṣe àtúnṣe àwọn ṣọ́ọ̀ṣì…

Ka siwaju

Lórí ọ̀rọ̀ Ìjínigbé: MACBAN bẹ Gómìnà Ọ̀yọ́ , Makinde, fi ẹ̀sùn kan Sunday Igboho fún fífi ìwé àṣẹ sílẹ̀ láti halẹ̀ mọ́ àwùjọ Fulani.

Lórí ọ̀rọ̀ Ìjínigbéc: MACBAN bẹ Gómìnà Oyo, Makinde, fi ẹ̀sùn kan Sunday Igboho fún fífi ìwé àṣẹ sílẹ̀ láti halẹ̀…

Ka siwaju

Awọn ọmọ Naijiria tó wà nínú atimọle ní orílẹ̀ èdè India tí ké gbàjarè síta, fi ẹ̀sùn kan Ile-iṣẹ ọlọ́pàá pé wọ́n tí Kọ wọn silẹ, Sọ pe O kéré tán 400 ọmọ Nàìjíríà ló wà nínú àhámọ́ ní Ibùdó Deportation.

Awọn ọmọ Naijiria tó wà nínú atimọle ní orílẹ̀ èdè India fi ẹ̀sùn kan Ile-iṣẹ ọlọ́pàá pé wọ́n tí Kọ…

Ka siwaju

Arìnrìn àjò Ìròyìn bí ó ṣe sá àsálà fún ẹ̀mí rẹ bí àwọn agbésùnmọ̀mí ṣe kọlù Nítòsí Ọgbà Ọ̀yọ́ àtijọ́ “Old Oyo National Park”.

Arìnrìn àjò Ìròyìn bí ó ṣe sá àsálà fún ẹ̀mí rẹ bí àwọn agbésùnmọ̀mí ṣe kọlù Nítòsí Ọgbà Ọ̀yọ́ àtijọ́…

Ka siwaju

Ọọ̀ni Adeyeye Eniitan Ogunwunsi Ọ̀jájá 11 tí késí ìjọba àpapọ̀ láti fòpin sí ètò àbò tó mẹ́hẹ àti bí ìwà jagidijagan àwọn ìwà ọ̀daràn mìíràn ṣe ń dàgbàsókè si lórílẹ̀ èdè Nàìjíríà.

Ọọ̀ni Adeyeye Eniitan Ogunwunsi Ọ̀jájá 11 tí késí ìjọba àpapọ̀ láti fòpin sí ètò àbò tó mẹ́hẹ àti bí ìwà…

Ka siwaju