Àwọn agbésùnmọ́mí jí ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn gbé nígbà àdúrà Jumu’ah ní àwọn àdúgbò kan ní Niger lẹ́yìn tí àwọn olùgbé kọ̀ láti san owó-orí tàbí láti tẹ̀lé àwọn ìlànà ẹ̀sìn kan — Gẹ́gẹ́ bí àwọn orísun ìròyìn ṣe sọ.

Àwọn agbésùnmọ́mí jí ọ̀pọ̀lọpọ̀ ènìyàn gbé nígbà àdúrà Jumu’ah ní àwọn àdúgbò kan ní Niger lẹ́yìn tí àwọn olùgbé kọ̀…

Ka siwaju

Gomina Kwara AbdulRazaq tó jẹ́ ọmọ Fulani dá wa dúró kò fàyè gba wa , láti bá àwọn agbésùnmọ̀mí jà lé wọn kúrò nínú igbó Kwara — Ìrú Ekun eléso ààbò ti Sunday Igboho.

Gomina Kwara AbdulRazaq jẹ́ ọmọ Fulani dá wa dúró kò fàyè gba wa , láti bá àwọn agbésùnmọ̀mí jà lé…

Ka siwaju

Ilé ẹjọ́ pàṣẹ pé kí wọ́n gba àwọn dúkìá Mínísítà Agbára iná mọ̀nàmọ́ná tẹ́lẹ̀ rí, Saleh Mamman’s lẹ́yìn tí wọ́n fún ní ẹ̀wọ̀n ọdún Márùndínláàdọ́rin 75.

Ilé ẹjọ́ pàṣẹ pé kí wọ́n gba àwọn dúkìá Mínísítà Agbára iná mọ̀nàmọ́ná tẹ́lẹ̀ rí, Saleh Mamman’s lẹ́yìn tí wọ́n…

Ka siwaju