Arákùnrin Alága Ìgbìmọ̀ Agbègbè Bungudu ní ìpínlẹ̀ Zamfara, tí àwọn ọ̀daràn agbésùnmọ́mí jí gbé, ti kú látàrí àwọn ọgbẹ́ ìbọn tí wọ́n yín fun lẹ́yìn ìkọlù wọn.

Arákùnrin Alága Ìgbìmọ̀ Bungudu ní ìpínlẹ̀ Zamfara, tí àwọn ọ̀daràn jí gbé, ti kú látàrí àwọn ọgbẹ́ ìbọn lẹ́yìn ìkọlù…

Ka siwaju

Ẹ lọ fa owó ìfipamọ́ yín yọ nílé ifowopamo kí ẹ sì ra àwọn ìbọn agbára-ńlá, láti dáàbò bo ara yín ni Aṣojú sòfin ìjọba ní Zamfara Hon. Abdulmalik Zubairu sọ fún àwọn ènìyàn agbègbè rẹ̀.

Ẹ lọ fa owó ìfipamọ́ yín yọ nílé ifowopamo kí ẹ sì ra àwọn ìbọn agbára-ńlá, láti dáàbò bo ara…

Ka siwaju

Awọn onijagidijagan Agbésùmọ́mí pa awọn ọlọpaa mẹrin ati awọn oṣiṣẹ aabo, wọn si ji Alaga Ijọba Ibilẹ Zamfara ati iyawo rẹ gbé lọ ni Bungudu.

Awọn onijagidijagan Agbésùmọ́mí pa awọn ọlọpaa mẹrin ati awọn oṣiṣẹ aabo, wọn si ji Alaga Ijọba Ibilẹ Zamfara ati iyawo…

Ka siwaju