China ṣe àkóbá fún orílẹ̀ èdè Iran bí ó ṣe fi amawomáwò ìmòye sí aṣọ ogun Iran.

Kàyéfì ńlá! Bí àwọn ọ̀gá Ológun Iran (IRGC) , ṣe bẹ̀rẹ̀ sí ní yọ okùn ipò ọ̀gá ológun àti àmí ìdánimọ̀ kúrò ní èjìká wọn tí wọ́n sì ń bọ́ aṣọ ológun dànù, láti máà fi ẹ̀mí ara wọn ṣòfò lẹ́hìn tí ìròyìn ìkìlọ̀ kan jáde síta wípé Orílẹ̀ èdè China ti se aṣọ ológun tí ó ní àmì ìdánimọ̀ nínú fún àwọn ológun Iran ti wọ́n bá ti lè wọ asọ náà àwọn ọmọ ogun Israeli yóò má tètè rí ibi tí wọn ba wà, gẹ́gẹ́ bí ohun a gbọ́ ni wípé China ti fi amawomáwò sí ara aṣọ ogún náà tí ó lè jẹ́ kí àwọn Israel🇮🇱 lè tètè ma rí ibikíbi tí àwọn ọmọ ogun Iran bá wà. Èyí ló fa ìbẹ̀rù bojo ti ó dé bá Orílẹ̀ èdè Iran 🇮🇷 lọ́wọ́ lọ́wọ́ báyìí .

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *