Mo gbà ki jẹ koriko lábẹ́ aṣáájú Mùsùlùmí ju kí n jẹ ẹran-adìẹ lábẹ́ aṣáájú tí kì í ṣe Mùsùlùmí lọ’ — Onímọ̀ ẹ̀sìn Islam Almaliky ṣe àtìlẹ́yìn fún àjọṣepọ̀ Tinubu àti Shettima Muslim – Muslim ticket.

Mo gbà ki jẹ koriko lábẹ́ aṣáájú Mùsùlùmí ju kí n jẹ ẹran-adìẹ lábẹ́ aṣáájú tí kì í ṣe Mùsùlùmí…

Ka siwaju

Amnesty International tún rọ àwọn aláṣẹ ní Nàìjíríà láti bọ̀wọ̀ fún àwọn ẹ̀tọ́ ọmọ-ìlú nígbà ìdìbò Gómìnà ní ìpínlẹ̀ Osun.

Amnesty International tún rọ àwọn aláṣẹ ní Nàìjíríà láti bọ̀wọ̀ fún àwọn ẹ̀tọ́ ọmọ-ìlú nígbà ìdìbò Gómìnà ní ìpínlẹ̀ Osun.…

Ka siwaju

Àwọn ọ̀daràn agbésùnmọ́mí gba 50 mílíọ̀nù náírà, àwọn ohun-mímu ẹlẹ́rìndòdò Malt àti oúnjẹ àti èso, kí wọ́n tó tú Adájọ́ Ilé-ẹjọ́ Gíga ti ìpínlẹ̀ Kebbi tí wọ́n jí gbé sílẹ̀ – Ìbátan rẹ̀ ṣàlàyé.

Àwọn ọ̀daràn agbésùnmọ́mí gba 50 mílíọ̀nù náírà, àwọn ohun-mímu ẹlẹ́rìndòdò Malt àti oúnjẹ èso kí wọ́n tó tú Adájọ́ Ilé-ẹjọ́…

Ka siwaju

Ọlọ́pàá Hisbah tí ìpínlẹ̀ Sokoto tí fi òfin de fífúnni ni ẹ̀bùn nígbà ètò ìfihàn ọkọ̀ àti ìyàwó àti lílo olorin DJ níbi ayẹyẹ ìgbéyàwó, wọ́n fi òfin de kí obìnrin jòkó sí ẹgbẹ awakọ̀ kẹ̀kẹ́ Napel.

Ọlọ́pàá Hisbah tí ìpínlẹ̀ Sokoto tí fi òfin de fífúnni ni ẹ̀bùn nígbà ètò ìfihàn ọkọ̀ àti ìyàwó àti lílo…

Ka siwaju

Ile-ẹjọ́ pàṣẹ fún Ọmọ-ogun Nàìjíríà láti dá àwọn ọmọ-ogun 70 tí wọ́n dá lẹ́bi ìṣọ̀tẹ̀ padà sí iṣẹ́, ó sì pàṣẹ kí wọ́n san owó-oṣù wọn láti oṣù Keje ọdún 2022.

Ile-ẹjọ́ pàṣẹ fún Ọmọ-ogun Nàìjíríà láti dá àwọn ọmọ-ogun 70 tí wọ́n dá lẹ́bi ìṣọ̀tẹ̀ padà sí iṣẹ́, ó sì…

Ka siwaju

Ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà Nàìjíríà tí fọwọ́sí ìwé òfin lati fi òfin de ìwàásù nínú àwọn ọkọ̀ èrò ìrìn àjò gbogboogbò, ẹni tí ó bá tapa sòfin yóò san Àádọ́ta ẹgbẹ̀rún náírà.

Ilé ìgbìmọ̀ aṣòfin àgbà Nàìjíríà tí fọwọ́sí ìwé òfin lati fi òfin de ìwàásù nínú àwọn ọkọ̀ èrò ìrìn àjò…

Ka siwaju

Àwọn oníjàgídíjàgan agbésùnmọ́mí tú wa sílẹ̀ kí àwọn ọmọ-ogun Nàìjíríà tó mú wa padà sílé – ọkàn lára Olùkọ́ láti Ọ̀yọ́ tí wọ́n gbà là sọ̀rọ̀.

Àwọn oníjàgídíjàgan agbésùnmọ́mí tú wa sílẹ̀ kí àwọn ọmọ-ogun Nàìjíríà tó mú wa padà sílé – ọkàn lára Olùkọ́ láti…

Ka siwaju