Trump ti dí ojú ọ̀nà tí orílẹ̀ èdè Iran lè gbà gbé epo rọ̀bì kọjá sí àwọn orílẹ̀ èdè mìíràn , bákan náà ni ó tún dí ibi tí Iran lè gbà gbé ọkọ ojú omi wọlé.

Ní alẹ́ ọjọ́ àìkú tíì ṣe ọjọ́ Kejìlá oṣù kẹrin ọdún 2026, ni iléeṣẹ́ ológun Amẹ́ríkà tún kéde wípé ìgbẹ́sẹ̀…

Ka siwaju

Ìjọba àpapọ̀ tí kó orúkọ àwọn ọmọ Nàìjíríà síta ,Tukur Mamu, Simon Njoku Ekpa, IPOB, àti àwọn gúrúpù12 mìíràn, tó ń ṣe ìrànlọ́wọ́ àti àtìlẹyìn fún àwọn agbésùnmọ̀mí.

Ìjọba àpapọ̀ tí kó gbogbo orúkọ àwọn ọmọ Nàìjíríà síta ,lára wọn ni Tukur Mamu, Simon Njoku Ekpa,tí ó jẹ…

Ka siwaju

Ẹ gba ìwé ìrìnnà lọ́wọ́ ẹnikẹ́ni tí ó bá ní òun kì í ṣe ọmọ Nàìjíríà mọ́, mínísítà ọ̀rọ̀ abẹ́lé Tunji Ojo pàṣẹ fún iléeṣẹ́ tó ń rí sí ìwọlé – jáde Nàìjíríà

Ìjọba àpapọ̀ tí fi òfin tuntun lélẹ̀, ẹnikẹ́ni tí ó bá ní òun kii se ọmọ Nàìjíríà mọ̀ ọ́, ijọba…

Ka siwaju

Ènìyàn márùn ni àwọn agbesunmobi tún ti pa lára wọn ni T. Dollar, ní Igbatoro ni ìpínlẹ̀ Ondo, Àwọn ará ìlú gbegi di òpópónà ọ́fíìsí Gómìnà ni Akure.

Àwọn ará ìlú se ìfẹ̀hónúhàn láti ké gbàjarè sì etí ìjọba bí àwọn agbesunmobi ṣe n pa àwọn ènìyàn lójoojúmọ́…

Ka siwaju

Olórí Ọlọ́dẹ àti àwọn Aṣọ́gbó márùn-ún pàdánù ẹ̀mí wọn ni Kwara bí àwọn agbesunmobi ṣe yabo wọn, tí wọ́n sì dáná sún ọkọ̀ àti ọ̀kadà wọn.

Fọ́nrán àti àwòrán tó jáde síta ṣe àfihàn bí àwọn agbesunmobi ṣe dáná sún ọkọ̀ àti ọ̀kadà àwọn Aṣọ́gbó náà,…

Ka siwaju

Àwọn agbesunmobi yawọ oko ọ̀sìn Adìẹ, wọn yinbon pa ìyá tó ni ọ̀sìn Adìẹ náà àti ọmọ rẹ̀ obìnrin ni agbègbè Igushin Ala Akure North (apá Àríwá Akure)

Àwọn agbesunmobi yinbon pa ìyá àti ọmọ rẹ̀ obìnrin lójú ẹsẹ bí wọ́n ṣe yawọ inú oko ọ̀sìn Adìẹ ni…

Ka siwaju