
Ìròyìn Tó ń lọ











Omo ilé ìwé tó ń kọ́ nípa ìmọ̀ ẹ̀rọ komputa ni wọn ri oku rẹ ni ile ìwé ni Ondo.…
Ka siwaju
Ìjọba ìpínlẹ̀ Kano tí fún Fatima Naseer Teemahcool, Alaga ti Gida-Gida TikTokers ti o ṣe afihan awọn aṣọ àwọ̀tẹ́lẹ̀ obìnrin…
Ka siwaju
Wike sọ èyí lásìkò ti o n gba àwọn òṣìṣẹ́ ìjọba, ìjọba Olómìnira náà lásìkò àbẹ̀wò ìtẹríba si ilé ìjọba…
Ka siwaju
Ààrẹ Bola Tinubu ti buwọ́lu N2bn ni àtìlẹyìn iranlọwọ owó gbà má bínú fún àwọn olóògbé 27 tí àwọn agbésùnmọ̀mí…
Ka siwaju
Awọn ará ìlú ti o ba oníròyìn sọrọ sọ pe ìṣẹ̀lẹ̀ náà wáyé ni ọsan ọjọ ìṣẹ́gun, ọjọ́ kejìdnlogbon oṣù…
Ka siwaju
Àwọn agbébọn yawọ ilé ìjọsìn Christ Apostolic church Eda Oniyo ní ìpínlẹ̀ Èkìtì, wón pa Pásítọ̀ ìjọ, wọ́n jí ọ̀pọ̀lọpọ̀…
Ka siwaju
Àwọn Agbéṣùmọ̀mí ti jí Ọgbẹni Bamsa Remilekun Daniel gbé nínú oko rẹ̀ ni Ègbé okun land. Ìròyìn fidi e mule…
Ka siwaju
Ileeṣẹ ọlọpaa lorilẹede Nàìjíríà ti bu ẹnu atẹ lu isẹlẹ iku ti afurasi kan, Mene Ogidi, ni Effurun, nipinlẹ Delta,…
Ka siwaju
Ìjọba ìpínlẹ̀ Ọ̀sun ti gbé Ọba Gbenga Oloyede kúrò lórí ìtẹ́ ọba gẹ́gẹ́ bí Apetumodu ti Ipetumodu ni ìjọba ìbílẹ̀…
Ka siwaju
Gomina ìpínlẹ̀ Adamawa Ahmadu Fintiri ti fi idi rẹ ìkọlù náà mulẹ pe ko din ju eniyan 29 ni wọn…
Ka siwaju