Gómìnà Ìpínlẹ̀ Kwara Abdrahman kéde pé òun yóò san N20milionu fún ẹnì kọ̀ọ̀kan àwọn ológun mẹta tí àwọn agbésùnmọ̀mí pa ni ọgbà ológun kemanji Kwara.

Gómìnà Ìpínlẹ̀ Kwara Abdrahman tí ṣe ìpinnu pé òun yóò san N20m fún ẹnì kọ̀ọ̀kan àwọn ọmọ ogun Nàìjíríà mẹta…

Ka siwaju

Ọba onípele tí ipele Ọ̀wọ̀ ń dunkoko ikú mọ́ ọmọbìnrin ọdún mọ́kànlélógún (21yrs),Látàrí bí Kehinde ṣe sọ pé ọba lo fún òun lóyún tí ọba sì ní kí òun ló yọ oyún náà, bí bẹ́ẹ̀ kọ́, òun yóò fi ikú ṣe ifá jẹ́.

Ọba onípele tí ipele ni ìjọba ìpínlẹ̀ Ọ̀wọ́ Ondo ń dunkoko ikú mọ́ ọmọ ọdún mọ́kànlélógún (21yrs) tí orúkọ rẹ…

Ka siwaju

Ọmọ Nàìjíríà tó wà ní UK, Adewale Anthony Sobogun ẹni ọdún (61yrs)rí ẹ̀wọ̀n ọdún méjìdínlọ́gbọ̀n(28yrs ) he, fún ẹ̀sùn ìfipábá ọmọdébìnrin méjì lò pọ̀.

Adewale Sobogun jẹ́ ẹni ọdún mọ́kànlélọ́gọ́ta, tí ó sì ti ń gbé orílẹ̀ èdè Biritiko( Uk) ti pẹ́. Ilé ẹjọ́…

Ka siwaju

Trump ti dí ojú ọ̀nà tí orílẹ̀ èdè Iran lè gbà gbé epo rọ̀bì kọjá sí àwọn orílẹ̀ èdè mìíràn , bákan náà ni ó tún dí ibi tí Iran lè gbà gbé ọkọ ojú omi wọlé.

Ní alẹ́ ọjọ́ àìkú tíì ṣe ọjọ́ Kejìlá oṣù kẹrin ọdún 2026, ni iléeṣẹ́ ológun Amẹ́ríkà tún kéde wípé ìgbẹ́sẹ̀…

Ka siwaju