Àpapọ̀ aṣojú ẹlẹ́sìn Kìrìsìtẹ́nì(CAN) sọ pé àwọn kò fi ìwé pé Sultan Sokoto Sa’ad Abubakar, láti wá ṣe bí adarí àwọn ọba níbi ìfilọ́lẹ̀ pápákọ̀ òfuurufú Chapel tuntun tí wọ́n fẹ sí ní Abuja.
Gẹ́gẹ́ bí ìròyìn tí àwọn CAN fi síta pé àwọn kò fi ìwé pé Sultan Sokoto síbi ayẹyẹ ìfilọ́lẹ̀ pápákọ̀ òfuurufú tuntun tí wọ́n fẹ sí ní Chapel Labuja.
Pẹ̀lú bí ìròyìn náà ṣe ń lọ lórí ayélujára pé àwọn kò fi ìwé pé Sultan Sokoto síbi ayẹyẹ ìfilọ́lẹ̀ pápákọ̀ òfuurufú tuntun.
Àwọn CAN fìdí ọ̀rọ̀ náà múlẹ̀ ni ọjọ́ Abemeta, tíì ṣe ọjọ́ kejìdínlógún oṣù kẹrin ọdún 2026, tí wọn sì yannayanna ọ̀rọ̀ náà pẹ̀lú ìròyìn tí akoroyin ijoba fi síta,pé ìròyìn tí àwọn kan fi síta pé àwọn CAN fi ìwé pé Sultan Sokoto wọn ní pe kò rí bẹ́ẹ̀ àwọn kò fi ìwé pé Sultan Sokoto síbi ayẹyẹ ìfilọ́lẹ̀ pápákọ̀ òfuurufú tuntun tí wọ́n fẹ sí ní Abuja pé ìròyìn eleje kan ló ń gbé kiri pé àwọn pé Sultan Sokoto Sa’ad Abubakar láti ṣoju gbogbo àwọn oba, irọ́ ni o àwa CAN kò fi ìwé pé Sultan Sokoto síbi ayẹyẹ ìfilọ́lẹ̀ pápákọ̀ òfuurufú tuntun tí a fe sì ni Chapel Labuja.












Saheed Junior
That man is gone