Skip to content
  • Monday, 11 May 2026
  • 11:51 pm
  • Tẹle wa
ÀṢÀKẸ́ NEWS
  • Ile
  • ÌRÒYÌN TÓ Ń LỌ
  • ÌṢÈLÚ
  • Ere Idaraya
  • ÌGBÉSÍ AYÉ
  • ÌRÒYÌN ÀGBÁYÉ
  • Ẹ̀KỌ́ ÈDÈ YORÙBÁ
Ìròyìn Tó ń lọ
Ààrẹ Tinubu rán gbákejì rẹ̀ Kashim Shettima lọ sí Ondo fún ti ayẹyẹ ọjọ́ ìbí ọgọ́rùn-ún ọdún DR. Reuben Fasoranti.
Àwọn Agbéṣùmọ̀mí jihadist JNIM ṣe ìkọlù tuntun mìíràn sí Mali, wọ́n pa ènìyàn.
Mínísítà tuntun tí wọ́n ṣẹ̀ṣẹ̀ yàn fún iná mọ̀nàmọ́ná Joseph Tegbe figbe ta, Mi kò ṣèlérí pé iná yóò fún oṣù mẹ́ta fún ọmọ Nàìjíríà o.
Arábìnrin Aláboyún tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Love Marcus bímọ sí ibùbá àwọn agbésùnmọ̀mí, lẹ́yìn ó san N77milionu.
Sínetọ̀ Adams Oshiomhole pé fún yíyọ Ààrẹ ilé ìgbìmọ̀ aṣojú sòfin Nàìjíríà Godwin Akpabio nípò.
ÌRÒYÌN TÓ Ń LỌ

Àwọn fulani darandaran pa olóyè ọ̀tún Balógun oluode Mutairu Oladosu ti okelade Ido Ìbàdàn sínú oko tomato rẹ̀.

Asake Apr 14, 2026 1

Àwọn fulani agbésùnmọ̀mí darandaran pa olóyè Otun Balógun Oluode Okelade ni Ìbàdàn.Ọba Wahab Olabamiji ti Okelade Ibadan lo fi idi…

Ka siwaju
ÌRÒYÌN ÀGBÁYÉ

China ṣe àkóbá fún orílẹ̀ èdè Iran bí ó ṣe fi amawomáwò ìmòye sí aṣọ ogun Iran.

Asake Apr 14, 2026 0

Kàyéfì ńlá! Bí àwọn ọ̀gá Ológun Iran (IRGC) , ṣe bẹ̀rẹ̀ sí ní yọ okùn ipò ọ̀gá ológun àti àmí…

Ka siwaju
ÌRÒYÌN ÀGBÁYÉ

Trump ti dí ojú ọ̀nà tí orílẹ̀ èdè Iran lè gbà gbé epo rọ̀bì kọjá sí àwọn orílẹ̀ èdè mìíràn , bákan náà ni ó tún dí ibi tí Iran lè gbà gbé ọkọ ojú omi wọlé.

Asake Apr 14, 2026 1

Ní alẹ́ ọjọ́ àìkú tíì ṣe ọjọ́ Kejìlá oṣù kẹrin ọdún 2026, ni iléeṣẹ́ ológun Amẹ́ríkà tún kéde wípé ìgbẹ́sẹ̀…

Ka siwaju
ÌRÒYÌN TÓ Ń LỌ

Seyi Makinde fẹ́ yọ Olubadan Ọba Abdulrasheed Adewolu Ladoja kúrò lórí ìtẹ́

Asake Apr 12, 2026 2

Àtẹ̀jáde kan tí Gómìnà Ìpínlẹ̀ Ekiti tẹ́lẹ̀ rí, Ayodele Fayose fi sí orí ìkànnì ayélujára abẹ́yẹfò x rẹ, lo tí…

Ka siwaju
ÌRÒYÌN TÓ Ń LỌ

Ìjọba àpapọ̀ tí kó orúkọ àwọn ọmọ Nàìjíríà síta ,Tukur Mamu, Simon Njoku Ekpa, IPOB, àti àwọn gúrúpù12 mìíràn, tó ń ṣe ìrànlọ́wọ́ àti àtìlẹyìn fún àwọn agbésùnmọ̀mí.

Asake Apr 12, 2026 0

Ìjọba àpapọ̀ tí kó gbogbo orúkọ àwọn ọmọ Nàìjíríà síta ,lára wọn ni Tukur Mamu, Simon Njoku Ekpa,tí ó jẹ…

Ka siwaju
ÌRÒYÌN TÓ Ń LỌ

Ẹ gba ìwé ìrìnnà lọ́wọ́ ẹnikẹ́ni tí ó bá ní òun kì í ṣe ọmọ Nàìjíríà mọ́, mínísítà ọ̀rọ̀ abẹ́lé Tunji Ojo pàṣẹ fún iléeṣẹ́ tó ń rí sí ìwọlé – jáde Nàìjíríà

Asake Apr 12, 2026 0

Ìjọba àpapọ̀ tí fi òfin tuntun lélẹ̀, ẹnikẹ́ni tí ó bá ní òun kii se ọmọ Nàìjíríà mọ̀ ọ́, ijọba…

Ka siwaju
ÌRÒYÌN TÓ Ń LỌ

Ènìyàn márùn ni àwọn agbesunmobi tún ti pa lára wọn ni T. Dollar, ní Igbatoro ni ìpínlẹ̀ Ondo, Àwọn ará ìlú gbegi di òpópónà ọ́fíìsí Gómìnà ni Akure.

Asake Apr 11, 2026 0

Àwọn ará ìlú se ìfẹ̀hónúhàn láti ké gbàjarè sì etí ìjọba bí àwọn agbesunmobi ṣe n pa àwọn ènìyàn lójoojúmọ́…

Ka siwaju
ÌRÒYÌN TÓ Ń LỌ

Olórí Ọlọ́dẹ àti àwọn Aṣọ́gbó márùn-ún pàdánù ẹ̀mí wọn ni Kwara bí àwọn agbesunmobi ṣe yabo wọn, tí wọ́n sì dáná sún ọkọ̀ àti ọ̀kadà wọn.

Asake Apr 10, 2026 3

Fọ́nrán àti àwòrán tó jáde síta ṣe àfihàn bí àwọn agbesunmobi ṣe dáná sún ọkọ̀ àti ọ̀kadà àwọn Aṣọ́gbó náà,…

Ka siwaju
ÀWỌN ÌRÒYÌN TÍ Ó NÍPA ÌRÒYÌN TÓ Ń LỌ

Àwọn agbesunmobi yawọ oko ọ̀sìn Adìẹ, wọn yinbon pa ìyá tó ni ọ̀sìn Adìẹ náà àti ọmọ rẹ̀ obìnrin ni agbègbè Igushin Ala Akure North (apá Àríwá Akure)

Asake Apr 10, 2026 3

Àwọn agbesunmobi yinbon pa ìyá àti ọmọ rẹ̀ obìnrin lójú ẹsẹ bí wọ́n ṣe yawọ inú oko ọ̀sìn Adìẹ ni…

Ka siwaju
ÌRÒYÌN TÓ Ń LỌ

Àwọn Agbéṣùmọ̀mí Bokoharam tún ti pa ọ̀gágun O. Braimah lénu isẹ́ bí wọn ṣe ṣe ìkọlù sí ọgbà ológun Benisheikh Borno

Asake Apr 9, 2026 0

Àwọn agbesunmobi ikọ̀ bokoharam pa Ọ̀gágún O. Braimah Alakoso ẹgbẹ́ ọmọ ogún Naijiria tì o jẹ́ ẹ̀ka 29 ikọ̀ ọgbà…

Ka siwaju

Posts pagination

1 … 6 7 8

Iroyin aipẹ

  • Ààrẹ Tinubu rán gbákejì rẹ̀ Kashim Shettima lọ sí Ondo fún ti ayẹyẹ ọjọ́ ìbí ọgọ́rùn-ún ọdún DR. Reuben Fasoranti.
  • Ìlú Èkó ṣe òfin ìrànlọ́wọ́ fún àwọn ènìyàn to ń lo iná mọnamọna n’ilu Èkó.
  • Àwọn Agbéṣùmọ̀mí jihadist JNIM ṣe ìkọlù tuntun mìíràn sí Mali, wọ́n pa ènìyàn.
  • Mínísítà tuntun tí wọ́n ṣẹ̀ṣẹ̀ yàn fún iná mọ̀nàmọ́ná Joseph Tegbe figbe ta, Mi kò ṣèlérí pé iná yóò fún oṣù mẹ́ta fún ọmọ Nàìjíríà o.
  • Arábìnrin Aláboyún tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Love Marcus bímọ sí ibùbá àwọn agbésùnmọ̀mí, lẹ́yìn ó san N77milionu.
Iroyin to Nlo
Ààrẹ Tinubu rán gbákejì rẹ̀ Kashim Shettima lọ sí Ondo fún ti ayẹyẹ ọjọ́ ìbí ọgọ́rùn-ún ọdún DR. Reuben Fasoranti.
May 11, 2026
Ìlú Èkó ṣe òfin ìrànlọ́wọ́ fún àwọn ènìyàn to ń lo iná mọnamọna n’ilu Èkó.
May 11, 2026
Àwọn Agbéṣùmọ̀mí jihadist JNIM ṣe ìkọlù tuntun mìíràn sí Mali, wọ́n pa ènìyàn.
May 10, 2026
Mínísítà tuntun tí wọ́n ṣẹ̀ṣẹ̀ yàn fún iná mọ̀nàmọ́ná Joseph Tegbe figbe ta, Mi kò ṣèlérí pé iná yóò fún oṣù mẹ́ta fún ọmọ Nàìjíríà o.
May 9, 2026
Arábìnrin Aláboyún tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Love Marcus bímọ sí ibùbá àwọn agbésùnmọ̀mí, lẹ́yìn ó san N77milionu.
May 9, 2026

Asọye aipẹ

  1. FUNMILAYO DELE on Ààrẹ Tinubu ti buwọ́lu N2bn owó gbà má bínú àtìlẹyìn ìrànlọ́wọ́ fún àwọn ènìyàn 27 tí àwọn agbésùnmọ̀mí pa ni March 29,ọjọ́ ìsinmi ọ̀pẹ (palm Sunday) ní Plateau .
  2. Saheed Junior on A kò fi ìwé pé Sultan Sokoto síbi ayẹyẹ ibi tí a ti fẹ́ ṣí pápákọ̀ òfuurufú Chapel tuntun ní Fct Labuja -CAN
  3. Remi Helen on Ọba olubadan Ladoja ń pète-pèrò láti yọ gómìnà Ìpínlẹ̀ ọ̀yọ́ Seyi Makinde.Ọ̀rọ̀ ń bọ́rọ̀ ń bọ̀ eégún aláré..
  4. Kamoli Ojekunle on Ọba onípele tí ipele Ọ̀wọ̀ ń dunkoko ikú mọ́ ọmọbìnrin ọdún mọ́kànlélógún (21yrs),Látàrí bí Kehinde ṣe sọ pé ọba lo fún òun lóyún tí ọba sì ní kí òun ló yọ oyún náà, bí bẹ́ẹ̀ kọ́, òun yóò fi ikú ṣe ifá jẹ́.
  5. Balogun Ismael on Ọba onípele tí ipele Ọ̀wọ̀ ń dunkoko ikú mọ́ ọmọbìnrin ọdún mọ́kànlélógún (21yrs),Látàrí bí Kehinde ṣe sọ pé ọba lo fún òun lóyún tí ọba sì ní kí òun ló yọ oyún náà, bí bẹ́ẹ̀ kọ́, òun yóò fi ikú ṣe ifá jẹ́.
Awọn ẹka
  • ÀWỌN ÌRÒYÌN TÍ Ó NÍPA
  • ÌGBÉSÍ AYÉ
  • ÌRÒYÌN ÀGBÁYÉ
  • ÌRÒYÌN TÓ Ń LỌ
  • ÌṢÈLÚ
  • Uncategorized
Iroyin ti oti le Ti padanu
News Mart logo

Ni pa wa

Shagam
info@asakenews.com
+212 710-380820
Iroyin Tuntun
Ààrẹ Tinubu rán gbákejì rẹ̀ Kashim Shettima lọ sí Ondo fún ti ayẹyẹ ọjọ́ ìbí ọgọ́rùn-ún ọdún DR. Reuben Fasoranti.
May 11, 2026
Ìlú Èkó ṣe òfin ìrànlọ́wọ́ fún àwọn ènìyàn to ń lo iná mọnamọna n’ilu Èkó.
May 11, 2026
Àwọn Agbéṣùmọ̀mí jihadist JNIM ṣe ìkọlù tuntun mìíràn sí Mali, wọ́n pa ènìyàn.
May 10, 2026
Mínísítà tuntun tí wọ́n ṣẹ̀ṣẹ̀ yàn fún iná mọ̀nàmọ́ná Joseph Tegbe figbe ta, Mi kò ṣèlérí pé iná yóò fún oṣù mẹ́ta fún ọmọ Nàìjíríà o.
May 9, 2026
Arábìnrin Aláboyún tí orúkọ rẹ̀ ń jẹ́ Love Marcus bímọ sí ibùbá àwọn agbésùnmọ̀mí, lẹ́yìn ó san N77milionu.
May 9, 2026
Awọn ẹka
  • ÀWỌN ÌRÒYÌN TÍ Ó NÍPA
  • ÌGBÉSÍ AYÉ
  • ÌRÒYÌN ÀGBÁYÉ
  • ÌRÒYÌN TÓ Ń LỌ
  • ÌṢÈLÚ
  • Uncategorized
Forukọsilẹ Fun Iwe Iroyin Wa

Se alabapin si iwe iroyin wa lati gba awọn nkan tuntun wa lesekese!

Copyright © 2026 Asake News | Design by Yaagboyaaju Tech

  • Home
  • About
  • Blog
  • Contact